Àpęę jęùn ki ję ibàję, Sùgbọn ilę sù lọ, ò súù lọ, Kini a ò sè bí ònję bá pę dé, Àriśé làrikà, Sùgbọn ęmi lè bọ, Baba ęni à má wipè, Bí ò pę tìtí, àléjò á dì ònilé, Sùgbọn áwọn ònìlúù tí mù ilę dì ọwọń, Ìbáwò ńàá ńí á ó dì ónílé? Ę tù'jù kàá, Ìjá dòpíń, ógúń ti tán, Dię dię lèkù ńjáwọ, Díę díę lęyę ńmù ọsáń, A ò mọyi Ọlọrùn yiò sè, Ni Kò ję ka binù kú, Isę ọwọ ęni lò mù ni làá, Ilę súù lọ, Igbá dìę nàâ la'ò kù A ki walę fùn adię ję, Ajùmọbi ò kan ti àrùn, Ki àlápá mù àpá rę lè, . (Poem: "ilę sù lọ" - by #olorunlekepoems ) #poetry #poem #yoruba #yorubapoetry #yorubapoem #tales
Comments
Post a Comment