ilę sù lọ


Àpęę jęùn ki ję ibàję,

Sùgbọn ilę sù lọ, ò súù lọ,

Kini a ò sè bí ònję bá pę dé,

Àriśé làrikà, Sùgbọn ęmi lè bọ,

Baba ęni à má wipè,

Bí ò pę tìtí, àléjò á dì ònilé,

Sùgbọn áwọn ònìlúù tí mù ilę dì ọwọń,

Ìbáwò ńàá ńí á ó dì ónílé?

Ę tù'jù kàá,

Ìjá dòpíń, ógúń ti tán,

Dię dię lèkù ńjáwọ,

Díę díę lęyę ńmù ọsáń,

A ò mọyi Ọlọrùn yiò sè,

Ni Kò ję ka binù kú,

Isę ọwọ ęni lò mù ni làá,

Ilę súù lọ, Igbá dìę nàâ la'ò kù

A ki walę fùn adię ję,

Ajùmọbi ò kan ti àrùn,

Ki àlápá mù àpá rę lè,

.

(Poem: "ilę sù lọ" - by #olorunlekepoems )

#poetry #poem #yoruba #yorubapoetry #yorubapoem  #tales

Comments

Popular posts from this blog

I Bleed for Benue